50 likes | 3.77k Views
GIRAMA. GBOLOHUN EDE YORUBA. KIN NI GBOLOHUN?. Gbolohun ni ipede ti o kun ti o ni oro-ise ti o si ni ise ti o n je. Gbolohun gbodo bere pelu leta nla , ki o si pari pelu ami idanuduro . Ona meji ni a le pin gbolohun si : 1. Ilana ihun 2. Ilana ilo.
E N D
GIRAMA GBOLOHUN EDE YORUBA
KIN NI GBOLOHUN? • Gbolohunniipedeti o kun ti o nioro-iseti o siniiseti o n je. • Gbolohungbodoberepeluletanla, ki o siparipeluamiidanuduro. • Onamejini a le pin gbolohunsi: • 1. Ilanaihun • 2. Ilanailo
IPINSOWOO GBOLOHUN NIPA IHUN • Awongbolohunabeihunni: • 1. GbolohunAlabode • 2. Gbolohunonibo • 3. GbolohunAlakanpo • 1. GBOLOHUN ALABODE: • Eyinigbolohunti a tun mo sigbolohunkukurutabigbolohuneleyooro-ise. • Apeere: Sade je isu.
Apeja pa ejaaro. • 2. GBOLOHUN ONIBO: Eyiniinugbolohunti a tifigbolohunkanboinugbolohunmiiran. • Apeere: • Efoti won ratigbo. • O darape mo wa. • 3. GBOLOHUN ALAKANPO: Inugbolohunyiini a tifioro-asopo so gbolohunmejipo.
Apeere: • Mo lo sioja • N koriatara = Mo lo siojasugbon n koriata.